Home Gospel Songs Mp3 Music Download & Lyrics: Sola Allyson – Agbonmagbe

Mp3 Music Download & Lyrics: Sola Allyson – Agbonmagbe

0
Sola Allyson – Imole Mp3 Music Download
Sola Allyson – Imole Mp3 Music Download

Sola Allyson – Agbonmagbe Mp3 Music Download & Lyrics

The Nigerian Christian/Gospel Artiste Sola Allyson Released a New Single Titled “Agbonmagbe”,

Sola Allyson – Agbonmagbe Mp3 Music Download

DOWNLOAD MUSIC

Download & Watch Video

Lyrics: Sola Allyson – Agbonmagbe

Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
E ni pase ore ti o Le tan loluwa
E ni pase ore ti o Le tan loluwa
Nibo lore tin wa bi o se odo baba wa
Nibo lore tin wa bi o se odo baba wa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe lo Kun
Agbonmagbe lo sa
Tori Agbonmagbe e ni baba to pase wa
Agbonmagbe lo Kun
Agbonmagbe lo sa
Tori Agbonmagbe e ni baba to pase wa
Baba olore, baba olore
Baba olore, baba olore
Ore ti o se salaye,
Ore ti ki tan, odo re ni won tin wa
Baba agbongbe
Ko seni to da bire
Musan musan lo re
Ta lo Le bi o lejo
A bu bu tan ni
Olola ta o Le ka, olore ti o se daye Le
Mo pa ya re olore mih
Ore ti o se pin ye Le
Iwo lo ni lowo, Mo pa ya re olore agbonmagbe
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
E ni pase ore ti o Le tan loluwa
E ni pase ore ti o Le tan loluwa
Nibo lore tin wa bi o se odo baba wa
Nibo lore tin wa bi o se odo baba wa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe lo Kun
Agbonmagbe lo sa
Tori Agbonmagbe e ni baba to pase wa
Agbonmagbe lo Kun
Agbonmagbe lo sa
Tori Agbonmagbe e ni baba to pase wa
Oba to fun ni la ye lo,
Olufunni ta o Le di lowo, ka si fun lo ti o Le lo tan laye
Iwo ni kan ni fun ni, eni to Sanu mih,
Eni to fun mi ni iranwo lo, Fi mi han bi tire, olore agbongbe
Mo ri osupa loke, orun na oke lo ti ran,
Irawo wa be o se ti e, osumare na fawo se ewa
Lati aye baye won ma tan, won si Le tan Lai Lai
Ore ti o Le tan, ewa ti o Le sa, ogo ti o Le ti Lai Lai
Iwo nikan lo ni ogo, Iwo ni kan lo ni ola
Mo juba re, olore agbongbe
Iru ore Yi ni mo fi irele okan bere baba gbe kan mih
Ma sa ma wa Leto re, olore agbongbe
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni oooore laaatodo oluwa
E ni pase ore ti o Le tan loluwa
E ni pase ore ti o Le tan loluwa
Nibo lore tin wa bi o se odo baba wa
Nibo lore tin wa bi o se odo baba wa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe lo Kun
Agbonmagbe lo sa
Tori Agbonmagbe e ni baba to pase wa
Agbonmagbe lo Kun
Agbonmagbe lo sa
Tori Agbonmagbe e ni baba to pase wa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Baba olore agbongbe, ore to wa lato do re ko Le tan Lai Lai
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
E ni pase ore ti o Le tan ni o baba mih
E ni pase ore ti o Le tan loluwa
From the north, from the east, from the west,
From the south, gbogbo ore latodo re ni baba mih
Nibo lore tin wa bi o se odo baba wa
Ila orun, Iwo orun, arinwa Ati gusu, gbogbo re latodo re ni o oluwa oo
Agbonmagbe e ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe lo Kun
Agbonmagbe lo sa
Tori Agbonmagbe e ni baba to pase wa
Agbonmagbe lo Kun
Agbonmagbe lo sa
Tori Agbonmagbe e ni baba to pase wa
End…

MUST READ:   Mp3 Music Download & Lyrics: Sola Allyson – Ibere