Home Gospel Songs Mp3 Music Download & Lyrics: Sola Allyson – Adun

Mp3 Music Download & Lyrics: Sola Allyson – Adun

0
Sola Allyson – Adun Mp3 Music Download
Sola Allyson – Adun Mp3 Music Download

Sola Allyson – Adun Mp3 Music Download & Lyrics

The Award Winning Nigerian Christian/Gospel Artiste Sola Allyson Released a New Single Titled “ Adun”,

Sola Allyson – Adun Mp3 Music Download

DOWNLOAD MUSIC

Download & Watch Video

Lyrics: Sola Allyson – Adun

Iran oju ti mo ri re oo
Ifihan ti mogba to yo simi ni yi ooo
Adun a po fun mi, ona a ma la daada
Mori adun mo ladun, were ladun wole de
Eyi mo bere ni mori, oluda mi sope
Edumare fadun s’ola mi, modupe adun ni 2xe.
Mo gb’adun de ooo, e tewo, e wa gba.
Eni ba fe koteti, oludani lo gbese to po gan ran mi wa
Boju woke ko r’adun, emi boju woke mo r’adun.
Ilakaka o sa simbe, orun logbadun yen wa.
Iran oju ti mo ri re oo
Ifihan ti mogba to yo simi ni yi ooo
Adun a po fun mi, ona a ma la daada
Bee ni
Mori adun mo ladun, were ladun wole de
Eyi mo bere ni mori, oluda mi sope
Edumare fadun s’ola mi, modupe adun ni 2xe.

MUST READ:   Download Music now: Jesus - Samsung feat. Mercy Chinwo